Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ọba Ásíríà,àwọn olùṣọ àgùntàn rẹ̀ ń tòògbé;awọn ọlọ́lá rẹ yóò máa gbé inú ekuru.Rẹ àwọn ènìyàn rẹ fọ́nká lórí àwọn òkè ńlá,tí ẹnikẹni kò sì kó wọn jọ.

Ka pipe ipin Náhúmù 3

Wo Náhúmù 3:18 ni o tọ