Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ilé-ìṣọ́ agbára rẹ yóò dàbí igi ọ̀pọ̀tọ́pẹ̀lú àkọ́pọ́n èso wọn;Nígbà tí wọ́n bá ń gbọ̀n wọ́n,ọ̀pọ̀tọ́ yóò sì bọ́ sí ẹnu àwọn ọ̀jẹun.

Ka pipe ipin Náhúmù 3

Wo Náhúmù 3:12 ni o tọ