Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ a kó o ní ìgbèkùno sì lọ sí oko ẹrú.Àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ rẹ̀ ni a ó fọ́ mọ́lẹ̀ní orí ìta gbogbo ìgboro.Wọ́n sì di ìbò nítorí àwọn ọlọ́lá rẹ̀ ọkùnrin,gbogbo àwọn ọlọ́lá rẹ ni a sì fi ẹ̀wọ̀n dè

Ka pipe ipin Náhúmù 3

Wo Náhúmù 3:10 ni o tọ