Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A pa á láṣẹ pé ìlú náà Èyí tí a ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ni kí a kó ní ìgbèkùn lọ.A ó sì mú un gòkè wáàti awọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ yóò ti ohùn bí ti oriri, ṣe amọ̀nà rẹ̀,wọn a sì máa lu àyà wọn.

Ka pipe ipin Náhúmù 2

Wo Náhúmù 2:7 ni o tọ