Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò mú ọláńlá Jákọ́bù padà sípògẹ́gẹ́ bí ọláńlá Ísírẹ́lìbí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn apanirun ti pa ibẹ̀ run,tí wọ́n sì ti run àwọn àjàrà wọn.

Ka pipe ipin Náhúmù 2

Wo Náhúmù 2:2 ni o tọ