Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 1:7-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Rere ni Olúwa,ààbò ní ọjọ ìpọ́njú.Òun sì tọ́jú àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀ lé e,

8. Ṣùgbọn pẹ̀lú ìkún omi ńlání òun yóò fi ṣe ìparun ibẹ̀ dé òpin;òkùnkùn yóò sì máa lépa àwọn ọ̀tá rẹ̀.

9. Kí ni ẹ̀yìn ń gbìmọ lòdì sí Olúwa?Òun yóò fi òpin sí i,Ìpọ́njú kì yóò wáyé ní ìgbà kejì

10. Wọn yóò sì lọ́lù papọ̀ bí ẹ̀gún òṣùṣùwọn yóò sì mu àmupara nínú ọtí wáìnì wọna ó sì run wọn gẹ́gẹ́ bi àkékù koríko gbígbẹ

Ka pipe ipin Náhúmù 1