Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Náhúmù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀,àwọn òkè kéékèèkéé sì di yíyọ́,ilẹ̀ ayé sì jóná níwájú rẹ̀,àní ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Náhúmù 1

Wo Náhúmù 1:5 ni o tọ