Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí òpùrọ́ àti ẹlẹ́tàn bá wà tí wọ́n sì wí pé,‘Èmi yóò sọ tẹ́lẹ̀ fún ọ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wáìnì àti bíà,’òun ni yóò tilẹ̀ ṣe wòlíì àwọn ènìyàn wọ̀nyí!

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:11 ni o tọ