Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Míkà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìré-òfin-kọjá Jákọ́bù ni gbogbo èyí,àti nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì.Kí ni ìré-òfin-kọjá Jákọ́bù?Ǹjẹ́ Samaríà ha kọ?Kí ni àwọn ibi gíga Júdà?Ǹjẹ́ Jérúsálẹ́mù ha kọ?

Ka pipe ipin Míkà 1

Wo Míkà 1:5 ni o tọ