Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 4:5-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. “Wò ó, èmi yóò rán wòlíì Èlíjà sí i yín, ki ọjọ́ ńlá, ọjọ́ ẹ̀rù Olúwa to dé:

6. Òun yóò sì pa ọkàn àwọn baba dà sí ti àwọn ọmọ, àti ọkàn àwọn ọmọ sì ti àwọn baba wọn, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, èmi yóò wá, èmi yóò sì fi ilẹ̀ náà gégùn-ún.”

Ka pipe ipin Málákì 4