Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Dájúdájú, ọjọ́ náà ń bọ̀; tí yóò máa jó bi iná ìléru. Gbogbo àwọn agbéraga, àti gbogbo àwọn olùṣe búburú yóò dàbí àgékù koríko: ọjọ́ náà tí ń bọ̀ yóò si jó wọn run,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí, “Ti ki yóò fi kù gbòǹgbò kan tàbí ẹ̀ka kan fún wọn.

Ka pipe ipin Málákì 4

Wo Málákì 4:1 ni o tọ