Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ènìyàn yóò ha ja Ọlọ́run ni olè bí? Ṣíbẹ̀ ẹ̀yin ti jà mí ní olè.“Ṣùgbọ́n ẹ̀yin béèrè pé, ‘Báwo ni àwa ṣe jà ọ́ ní olè?’“Nípa ìdámẹ́wàá àti ọrẹ.

Ka pipe ipin Málákì 3

Wo Málákì 3:8 ni o tọ