Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ó sì súnmọ́ yin fún ìdájọ́. Èmi yóò sì yára ṣe ẹlẹ́rìí sí àwọn oṣó, sí àwọn panṣágà, sí àwọn abúra èké, àti àwọn tí ó fi ọ̀yà alágbàṣe dù ú, àti àwọn tí ó ni àwọn opó àti àwọn aláìní baba lara, àti sí ẹni tí kò jẹ́ kí àlejò rí ìdájọ́ òdodo gbà, tí wọn kò sì bẹ̀rù mi,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Ka pipe ipin Málákì 3

Wo Málákì 3:5 ni o tọ