Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wò ó, Èmi yóò ran ìránṣẹ mi, yóò si tún ọ̀nà ṣe ṣáájú mi. Nígbà náà ni Olúwa, tí ẹ̀yin ń wa, yóò dé ni òjijì sí tẹ́ḿpìlì rẹ̀; àní oníṣẹ́ májẹ̀mú náà, tí inú yín dùn sí, yóò dé,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Ka pipe ipin Málákì 3

Wo Málákì 3:1 ni o tọ