Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí ètè àlùfáà ní a ti máa pa ìmọ̀ mọ́, kí àwọn ènìyàn lè máa wá ìtọ́ni ni ẹnu rẹ̀: nítorí òun ni iransẹ Olúwa àwọn ọmọ ogun.

Ka pipe ipin Málákì 2

Wo Málákì 2:7 ni o tọ