Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Májẹ̀mu mi wà pẹ̀lú rẹ̀, májẹ̀mu ti ìyè àti àlàáfíà wà pẹ̀lú rẹ̀; mo sì fi wọn fún un, nítorí bíbẹ̀rù tí ó bẹ̀rù mi, tí ẹ̀rù orúkọ mi sì bà á.

Ka pipe ipin Málákì 2

Wo Málákì 2:5 ni o tọ