Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdà ti ń hùwà àrékérekè, a sì ti hùwà ìríra ní Ísírẹ́lì àti ni Jérúsálẹ́mù: nítorí Júdà tí ṣe eyi ti ó lè sọ ibi mímọ́ Olúwa di aláìmọ́ nípa gbígbé ọmọbìnrin ọlọ́run àjèjì ni ìyàwó.

Ka pipe ipin Málákì 2

Wo Málákì 2:11 ni o tọ