Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Málákì 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n ègún ni fún ẹlẹ́tàn náà, tí ó ni akọ nínú ọ̀wọ́ ẹran rẹ̀, tí ó sì ṣe ìlérí láti fi lélẹ̀ tí ó sì fi ẹ̀ran tó lábùkù rúbọ sí Olúwa; nítorí Ọba ńlá ni Èmi,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí, “ẹ̀rù sì ni orúkọ mi láàrin àwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Málákì 1

Wo Málákì 1:14 ni o tọ