Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sọ fún Árónì pé, “Wá sí ibi pẹpẹ kí o sì rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ àti ẹbọ sísun rẹ, kí o sì ṣe ètùtù fún ara rẹ àti fún àwọn ènìyàn; rú ẹbọ ti àwọn ènìyàn náà, kí o sì ṣe ètùtù fún wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ”

Ka pipe ipin Léfítíkù 9

Wo Léfítíkù 9:7 ni o tọ