Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 9:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè sí àwọn ènìyàn, ó sì súre fún wọn. Lẹ́yìn tó sì ti rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ẹbọ sísun àti ẹbọ àlàáfíà, ó sọ̀kalẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 9

Wo Léfítíkù 9:22 ni o tọ