Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì mú ẹbọ tó jẹ́ ti àwọn ènìyàn wá. Ó mú òbúkọ èyí tó dúró fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn ó sì pa á, ó fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ti àkọ́kọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 9

Wo Léfítíkù 9:15 ni o tọ