Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 8:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì mú díẹ̀ lára òróró ìtasórí àti díẹ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ láti orí pẹpẹ, ó wọ́n sára àwọn ọmọ Árónì àti aṣọ rẹ̀, ó sì tún wọ́n sára àwọn ọmọ Árónì àti aṣọ wọn. Bẹ́ẹ̀ ní Mósè ya Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú aṣọ wọn sí mímọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 8

Wo Léfítíkù 8:30 ni o tọ