Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 8:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú ọ̀rá ẹran náà, ìrù rẹ̀ tí ó lọ́ràá, gbogbo ọ̀rá tó wà lára nǹkan inú àti èyí tó bo ẹ̀dọ̀, kíndìnrín méjèèjì àti ọ̀rá wọn pẹ̀lú itan ọ̀tún.

Ka pipe ipin Léfítíkù 8

Wo Léfítíkù 8:25 ni o tọ