Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 8:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè pa akọ màlúù náà, ó sì ti ìka bọ inú ẹ̀jẹ̀ náà, ó fi sí orí gbogbo ìwo pẹpẹ láti wẹ pẹpẹ náà mọ́. Ó da ìyóòkù ẹ̀jẹ̀ náà sí ìṣàlẹ̀ pẹpẹ. Bẹ́ẹ̀ ní ó ṣe yà á sí mímọ́ láti ṣe ètùtù fún un.

Ka pipe ipin Léfítíkù 8

Wo Léfítíkù 8:15 ni o tọ