Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 7:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́jọ́ tí a fi òróró yàn wọ́n, ni Olúwa ti pa á láṣẹ pé kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa fún wọn ní àwọn nǹkan wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn ìgbà gbogbo fún àwọn ìran tó ń bọ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:36 ni o tọ