Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 7:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ọrẹ àlàáfíà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo ti ya igẹ̀ tí a fi àti itan tí ẹ mú wá sọ́tọ̀ fún Árónì àlùfáà àti àwọn ọmọ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn ní gbogbo ìgbà láti ọ̀dọ̀ ara Ísírẹ́lì.’ ”

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:34 ni o tọ