Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹran tí ó bá ti kan ohun tí a kà sí àìmọ́, sísun ni kí ẹ sun ún. Ẹnikẹ́ni tí a ti kà sí mímọ́ le è jẹ nínú ẹran tí ó kù.

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:19 ni o tọ