Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹran ọrẹ àlàáfíà ti ọpẹ́ yìí ni wọ́n gbọdọ̀ jẹ ní ọjọ́ gan-an tí wọ́n rúbọ, kò gbọdọ̀ ṣẹ́ ẹran kankan kù di àárọ̀ ọjọ́ kéjì.

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:15 ni o tọ