Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá dẹ́ṣẹ̀ báyìí tó sì jẹ̀bi, ó gbọdọ̀ dá ohun tó jí tàbí ohun tó fi agbára gbà, tàbí ohun tí a fi sí ìkáwọ́ rẹ̀, tàbí ohun tó sọnù tó rí he,

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:4 ni o tọ