Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọkùnrin Árónì tí yóò rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àlùfáà tí a fi òróró yàn ni yóò rú ẹbọ náà. Ó jẹ́ ìpín ti Olúwa títí láé, wọn sì gbọdọ̀ sun ún pátapáta.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:22 ni o tọ