Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ẹnikẹ́ni bá dẹ́ṣẹ̀ tí ó sì ṣe àìsòótọ́ sí Olúwa nípa títan ẹnìkejì rẹ̀ lórí ohun tí wọ́n fi sí ìkáwọ́ tàbí tí wọ́n fi pamọ́ sí i lọ́wọ́, tàbí bí ó bá jalè, tàbí kí ó yan ẹnìkejì rẹ̀ jẹ,

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:2 ni o tọ