Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iná tó wà lórí pẹpẹ gbọdọ̀ máa jó, kò gbọdọ̀ kú, ní àràárọ̀ ni kí àlùfáà máa to igi si, kí ó sì to ẹbọ sísun sórí iná, kí ó sì máa sun ọ̀rá ẹran ẹbọ àlàáfíà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:12 ni o tọ