Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí àlùfáà sì wọ èwù funfun rẹ̀ pẹ̀lú àwọ̀tẹ́lẹ̀ lára rẹ̀, yóò sì kó eérú tó wà nibi ẹbọ sísun tí iná ti jó lórí pẹpẹ, sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 6

Wo Léfítíkù 6:10 ni o tọ