Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ó mú àgbò kan láti inú agbo ẹran wá sọ́dọ̀ àlùfáà, fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àgbò tí kò lábùkù tí ó sì níye lórí bí iye owó ibi mímọ́. Báyìí ni àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún ẹni náà, fún àṣìṣe tí ó ṣe láìmọ̀, a ó sì dári jìn-ní.

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:18 ni o tọ