Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó ṣe àtúnṣe nítorí ohun tí ó ti kùnà láti ṣe ní ti àwọn ohun mímọ́ Olúwa, kí ó sì fi ìdá márùn-ún kún iye ohun tí ó kùnà láti ṣe nípa ohun mímọ́ Olúwa kí ó sì kó gbogbo rẹ̀ fún àlùfáà, ẹni tí yóò ṣe ètùtù fún un pẹ̀lú àgbò fún ẹbọ ẹ̀bi, a ó sì dárí jìn-ní.

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:16 ni o tọ