Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó gbé e wá sí ọ̀dọ̀ àlùfáà, àlùfáà yóò sì bu ẹ̀kúnwọ́ ìyẹ̀fun gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìrántí, kí ó sì sun ún lórí pẹpẹ, gẹ́gẹ́ bí ẹbọ tí a fi iná sun sí Olúwa. Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:12 ni o tọ