Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn èyí àlùfáà yóò wá rú ẹbọ sísun gẹ́gẹ́ bí ìlànà, yóò sì ṣe ètùtù fún un nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ṣẹ̀, a ó sì dárí jìn-ní.

Ka pipe ipin Léfítíkù 5

Wo Léfítíkù 5:10 ni o tọ