Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó mú un wá ṣíwájú Olúwa ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. Kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, kí ó sì pa á níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:4 ni o tọ