Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 4:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó yọ gbogbo ọ̀rá rẹ̀ bó ti yọ ọ̀rá lára ọ̀dọ́-àgùntàn ọrẹ àlàáfíà, àlùfáà yóò sì sun ún ní orí pẹpẹ, lórí ọrẹ tí a fi iná sun sí Olúwa. Báyìí ni àlùfáà yóò se ètùtù fún ẹni náà, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó sẹ̀, a ó sì dáríjìn-ín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:35 ni o tọ