Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó sì mú díẹ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ náà sórí ìwo pẹpẹ tó wà níwájú Olúwa nínú àgọ́ ìpàdé. Ìyòókù ẹ̀jẹ̀ náà ni kí ó dà sí ìṣàlẹ̀ pẹpẹ ẹbọ sísun ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:18 ni o tọ