Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí túmọ̀ sí pé gbogbo ìyókù akọ màlúù náà ni kí ẹ gbé jáde síta lẹ́yìn ibùdó sí ibi tí a sọdi mímọ́ níbi tí à ń da eérú sí, kí ẹ sì sun wọ́n lórí iná igi, níbi eérú tí a kó jọ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:12 ni o tọ