Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì mú wá nínú ẹbọ àlàáfíà náà, fún ẹbọ tí a fi iná se sí Olúwa; ọ̀rá rẹ̀ àti gbogbo ìrù rẹ̀ tí ó ní ọ̀rá, òun ni kí o mú kúrò súnmọ́ egungun ẹ̀yìn àti ọ̀rá tí ó bo ìfun lórí; àti gbogbo ọ̀rá tí ń bẹ lára ìfun.

Ka pipe ipin Léfítíkù 3

Wo Léfítíkù 3:9 ni o tọ