Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, kí ó sì pa á ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ. Nígbà náà ni àwọn ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà yóò wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹran náà yí pẹpẹ ká.

Ka pipe ipin Léfítíkù 3

Wo Léfítíkù 3:2 ni o tọ