Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 27:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnìkan tí ó jẹ́ ẹ̀jẹ́ bá tálákà púpọ̀ débi pé kò lè san iye owó náà, kí a mú ẹni náà wá ṣíwájú àlùfáà, àlùfáà yóò sì dá iye owó tí ó lè san lé e gẹ́gẹ́ bí agbára ẹni náà tí ó jẹ́ ẹ̀jẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:8 ni o tọ