Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 27:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí iye owó ọkùnrin láti ọmọ ogún ọdún sí ọgọ́ta ọdún jẹ́ àádọ́ta òṣùnwọ̀n Ṣékélì fàdákà, gẹ́gẹ́ bí oṣùwọ̀n sékélì ti ibi mímọ́ Olúwa;

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:3 ni o tọ