Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn èrè oko yín yóò pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ẹ̀yin ó máa jẹ èrè ọdún tí ó kọjá, ẹ̀yin ó sì kó wọn jáde: kí ẹ̀yin lè rí àyè kó túntún sí.

Ka pipe ipin Léfítíkù 26

Wo Léfítíkù 26:10 ni o tọ