Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 26:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ mọ ère òrìsà, tàbí kí ẹ̀yin gbe ère kalẹ̀ tàbí kí ẹ̀yin gbẹ́ ère òkúta: kí ẹ̀yin má sì gbẹ́ òkúta tí ẹ̀yin yóò gbé kalẹ̀ láti sìn. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 26

Wo Léfítíkù 26:1 ni o tọ