Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 25:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Bí arákùnrin yín kan bá talákà tí kò sì le è pèsè fún àìní ara rẹ̀: ẹ pèsè fún un bí ẹ ti ń ṣe fún àwọn àlejò tàbí àwọn tí ẹ gbà sílé: kí ó baà leè máa gbé láàrin yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 25

Wo Léfítíkù 25:35 ni o tọ