Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 25:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí iye ọdún rẹ̀ bá gùn, kí iye owó rẹ̀ pọ̀, bí iye ọdún rẹ̀ bá kúrú, kí iye owó rẹ̀ kéré, torí pé ohun tí ó tà gan an ní iye èso rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 25

Wo Léfítíkù 25:16 ni o tọ