Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 25:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àádọ́ta ọdún ni yóò jẹ́ ọdún ìdásílẹ̀ fún yín. Ẹ má ṣe gbin ohunkóhun, ẹ kò sì gbọdọ̀ kórè ohun tí ó hù fúnrarẹ̀ tàbí kí ẹ kórè ọgbà àjàrà tí ẹ kò dá.

Ka pipe ipin Léfítíkù 25

Wo Léfítíkù 25:11 ni o tọ